×
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal

Mimu Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Isẹ Awa Ẹda ( Taohiidul-Uluuhiyyah ) (Èdè Yorùbá)

Itumọ Mimu Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Isẹ Awa Ẹda ( Taohiidul-Uluuhiyyah ) pẹlu alaye wipe Taohiid yii ni o maa nda ija silẹ laarin awọn ojisẹ ati awọn ijọ wọn

Play

Awon ogbifo miran 1

معلومات المادة باللغة العربية