×
New!

Bayan Al Islam Encyclopedia Mobile Application

Get it now!

Pípèsè: Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro

Ola ti o wa fun Eni ti o ba mo Olohun lokan (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi je ki a mo Pataki ki Musulumi mo Olohun re ni okan soso ki o si doju ijosin ko Olohun naa. Mimo Olohun ni okan (Taoheed) ni ipile esin, ohun si ni ohun ti o ye ki Musulumi moju to julo.

Play
معلومات المادة باللغة العربية