1- Awọn akori ọrọ ti o jẹyọ ni abala yii ni wọnyii: (i).Itumọ sise Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ. (ii). Alaye lori awọn ti wọn lodi si Sunna nibi ilana yii. 2- Alaye nipa ilana awọn ti won tẹle Sunna nibi orukọ Ọlọhun ati awọn iroyin Rẹ.
Agbedegbẹyọ ti Íńtánẹ́ẹ̀tì fun awọn ohun èlò kan ti a ṣẹṣa fun ṣíṣe àlàyé ìtumọ̀ Isilaamu ati fifi mọ ẹlòmíràn pẹ̀lú àwọn èdè