×
Pípèsè: Qomorudeen Yunus

Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa awon nkan kan, ninu won niyi: (1) Musulumi ni eni ti iwa daradara ti Islam pepe si ba han ni ara re. (2) Ninu ohun ti esin Islam pase re ni ki Musulumi maa se aponle gbogbo eniyan, eni ti o je Musulumi ati eni ti kiise Musulumi, ki o si maa dun won ninu.

Play
معلومات المادة باللغة العربية