×
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal

Awọn Ohun Eewọ ti apakan ninu awọn Musulumi fi ọwọ yẹpẹrẹ mu (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ nipa awọn ohun eewọ ti o ti di gbajumọ ni awujọ wa ni ode oni pẹlu ẹri ikilọ awọn iwa ibajẹ yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.

Play
معلومات المادة باللغة العربية