×
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal

Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo, (ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii, (iii) Majẹmu Rukiya, (iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun, (v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ, ọmọde ati lati fi wa iwosan.

Play
معلومات المادة باللغة العربية