1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
Agbedegbẹyọ ti Íńtánẹ́ẹ̀tì fun awọn ohun èlò kan ti a ṣẹṣa fun ṣíṣe àlàyé ìtumọ̀ Isilaamu ati fifi mọ ẹlòmíràn pẹ̀lú àwọn èdè