1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ. 2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ di Ọlọhun. 3- Ọrọ nipa isẹ ipepe anọbi Isa pẹlu isẹ ayanu rẹ, ati wipe Iru ẹlẹsin wo ni Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a].
Agbedegbẹyọ ti Íńtánẹ́ẹ̀tì fun awọn ohun èlò kan ti a ṣẹṣa fun ṣíṣe àlàyé ìtumọ̀ Isilaamu ati fifi mọ ẹlòmíràn pẹ̀lú àwọn èdè