×
Pípèsè: Isa Akindele Solahudeen

Pataki Imo ati Ojuse Awon Onimimo tele ati nisisiyi ni Nigeria (Èdè Yorùbá)

Koko oro inu waasi yi ni alaye lori pataki imo ati pataki awon onimimo, bakannaa ni bi o se se pataki to ki apa kan ninu awon Musulumi gbiyanju lati wa imo leyinnaa ki won se awon eniyan ni anfaani pelu imo won fun atunse awujo.

Play
معلومات المادة باللغة العربية