×
New!

Bayan Al Islam Encyclopedia Mobile Application

Get it now!

Pípèsè: Qomorudeen Yunus

Iyato ti o wa laarin Itoju Arun ni Ilana Islam ati Oogun Awon Elebo (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi so wipe awon nkan itoju arun ti Olohun se fun awa Musulumi po pupo ju ki a maa wa iranlowo nibi ohun ti o wa lodo awon keeferi ati elebo lo. O si so die ninu awon nkan iwosan naa, gege bi o ti so nipa awon eyi ti o je eewo fun Musulumi bii awon nkan ebo.

Play
معلومات المادة باللغة العربية