×
New!

Bayan Al Islam Encyclopedia Mobile Application

Get it now!

Pípèsè: Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro

Alaye Lori Awon Iruju ti o nbe fun Awon Eniyan Kan nipa Wiwa Ategun (At-tawassul) (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori alaye ni ekunrere lori awon iruju ti o nbe fun awon eniyan kan nipa awon ohun ti o leto ki Musulumi maa fi se ategun si odo Olohun ati awon nkan ti ko leto nigbati o ba npe Olohun.

Play
معلومات المادة باللغة العربية