×
New!

Bayan Al Islam Encyclopedia Mobile Application

Get it now!

Pípèsè: Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro

Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yii da lori sise aseju tabi aseeto ninu ẹsin eyi ti o wọpọ laarin awọn ọdọ, ti olubanisọrọ si jẹ ki a mọ awọn okunfa rẹ gẹgẹ bii: 1-Aini imọ ẹsin ti o kun to, 2-Agbọye odi lori ẹsin, 3-lilero aburu si awọn onimimọ, 4-Igbarata ẹsin, 5- Sisọ gbogbo nkan di Bidi’ah, 6- fifun ilẹ mọni nibiti igbalaye wa ki gbolohun pe meji nibẹ. Ni igbẹyin, olubanisọrọ jẹ ki a mọ wipe gbigba Sunnah mu nikan ni o le yọ wa nibi aseju tabi aseeto.

Play
معلومات المادة باللغة العربية