×
New!

Bayan Al Islam Encyclopedia Mobile Application

Get it now!

Pípèsè: Abdul-jeleel Alagufon

Awon Alaye Esin Nipa Igbagbo si Ayanmon (Kadara) (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi: (1) Itumo Ayanmo. (2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo. (3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise. (4) Awon ipele Ayanmo. (5) Ninu awon idi ti Olohun fi se Ayanmo ni ohun asiri ati ipamo.

Play
معلومات المادة باللغة العربية