Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.
Agbedegbẹyọ ti Íńtánẹ́ẹ̀tì fun awọn ohun èlò kan ti a ṣẹṣa fun ṣíṣe àlàyé ìtumọ̀ Isilaamu ati fifi mọ ẹlòmíràn pẹ̀lú àwọn èdè