Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo, (ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii, (iii) Majẹmu Rukiya, (iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun, (v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ, ọmọde ati lati fi wa iwosan.
Agbedegbẹyọ ti Íńtánẹ́ẹ̀tì fun awọn ohun èlò kan ti a ṣẹṣa fun ṣíṣe àlàyé ìtumọ̀ Isilaamu ati fifi mọ ẹlòmíràn pẹ̀lú àwọn èdè