Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii: 1. Titẹle asẹ rẹ. 2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo. 3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi. 4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati didaabo bo Sunnah rẹ.
Agbedegbẹyọ ti Íńtánẹ́ẹ̀tì fun awọn ohun èlò kan ti a ṣẹṣa fun ṣíṣe àlàyé ìtumọ̀ Isilaamu ati fifi mọ ẹlòmíràn pẹ̀lú àwọn èdè