×
Pípèsè: Abdur Rahman Muhammadul Awwal

Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ (Èdè Yorùbá)

1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.

Play
معلومات المادة باللغة العربية