×
Příprava: Sharafuddeen Gbadebọ Raji

Idajọ Irun ti a fi n wa Ojo (Sọlaatul-istiskaai) (Èdè Yorùbá)

Eyi ni ẹkunrẹrẹ alaye lori bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se maa n ki Irun Itọrọ Ojo pẹlu sise afihan awọn orisirisi ọna ti o gba se adua lati tọrọ ojo nigba aye rẹ.

Play
معلومات المادة باللغة العربية