×
ahoboa: Abdur Rahman Muhammadul Awwal

Ọla ti nbẹ fun kika Alukurani Alapọnle (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yi sọ nipa ohun ti a npe ni Alukuraani pẹlu awọn ẹri lati inu ayọka rẹ, ọrọ si tun waye lori awọn ọla ti o wa fun kika rẹ ati awọn ẹkọ ti o rọ mọ kike rẹ.

Play
معلومات المادة باللغة العربية